ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 2:33, 34
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 Èèyàn rẹ tí mi ò mú kúrò lẹ́nu sísìn níbi pẹpẹ mi yóò mú kí ojú rẹ di bàìbàì, yóò sì kó ẹ̀dùn ọkàn bá ọ,* idà àwọn èèyàn ló máa pa èyí tó pọ̀ jù lára àwọn ará ilé rẹ.+ 34 Ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí àwọn ọmọkùnrin rẹ méjèèjì, Hófínì àti Fíníhásì yóò jẹ́ àmì fún ọ: Ọjọ́ kan náà ni àwọn méjèèjì máa kú.+

  • 1 Sámúẹ́lì 4:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Yàtọ̀ síyẹn, wọ́n gba Àpótí Ọlọ́run, àwọn ọmọ Élì méjèèjì, Hófínì àti Fíníhásì sì kú.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́