-
1 Sámúẹ́lì 4:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Aya ọmọ rẹ̀, ìyẹn ìyàwó Fíníhásì wà nínú oyún, kò sì ní pẹ́ bímọ. Nígbà tó gbọ́ ìròyìn pé wọ́n ti gba Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ àti pé bàbá ọkọ rẹ̀ àti ọkọ rẹ̀ ti kú, ó tẹ̀ ba, lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ ó bẹ̀rẹ̀ sí í rọbí, ó sì bímọ.
-