1 Sámúẹ́lì 5:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ọwọ́ Jèhófà le mọ́ àwọn ará Áṣídódì, ó kó ìyọnu bá wọn, ó sì ń fi jẹ̀díjẹ̀dí* kọ lu Áṣídódì àti àwọn ìpínlẹ̀ rẹ̀.+
6 Ọwọ́ Jèhófà le mọ́ àwọn ará Áṣídódì, ó kó ìyọnu bá wọn, ó sì ń fi jẹ̀díjẹ̀dí* kọ lu Áṣídódì àti àwọn ìpínlẹ̀ rẹ̀.+