ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 8:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Dáfídì ń jọba lórí gbogbo Ísírẹ́lì,+ Dáfídì ń dá ẹjọ́ bó ṣe tọ́, ó sì ń ṣe òdodo+ sí gbogbo àwọn èèyàn rẹ̀.+

  • 1 Àwọn Ọba 3:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Ni Sólómọ́nì bá sọ pé: “O ti fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí ìránṣẹ́ rẹ, Dáfídì bàbá mi, lọ́nà tó ga, bó ṣe rìn níwájú rẹ ní òtítọ́ àti ní òdodo pẹ̀lú ọkàn tó dúró ṣinṣin. Títí di òní yìí, ò ń fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ kan náà hàn sí i lọ́nà tó ga tí o fi fún un ní ọmọkùnrin kan láti jókòó sórí ìtẹ́ rẹ̀.+

  • 1 Àwọn Ọba 9:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Ní tìrẹ, tí o bá rìn níwájú mi bí Dáfídì bàbá rẹ ṣe rìn+ pẹ̀lú òtítọ́ ọkàn+ àti ìdúróṣinṣin,+ tí ò ń ṣe gbogbo ohun tí mo pa láṣẹ fún ọ,+ tí o sì ń pa àwọn ìlànà mi àti àwọn ìdájọ́ mi mọ́,+

  • 1 Àwọn Ọba 15:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Dáfídì ṣe ohun tí ó tọ́ ní ojú Jèhófà, ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀, kò kúrò nínú gbogbo ohun tí Ó pa láṣẹ fún un, àfi nínú ọ̀ràn Ùráyà ọmọ Hétì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́