-
Ẹ́kísódù 15:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ìwọ yóò mú wọn wá, ìwọ yóò sì gbìn wọ́n sí òkè ogún rẹ,+
Ibi tó fìdí múlẹ̀ tí o ti pèsè kí ìwọ fúnra rẹ lè máa gbé, Jèhófà,
Ibi mímọ́ tí o fi ọwọ́ rẹ ṣe, Jèhófà.
-