Sefanáyà 1:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Fàdákà wọn tàbí wúrà wọn kò ní lè gbà wọ́n ní ọjọ́ ìbínú ńlá Jèhófà;+Torí ìtara rẹ̀ tó ń jó bí iná máa jó gbogbo ayé run,+Nítorí ó máa pa àwọn èèyàn ayé nípakúpa, àní á pa wọ́n yán-án yán-án.”+
18 Fàdákà wọn tàbí wúrà wọn kò ní lè gbà wọ́n ní ọjọ́ ìbínú ńlá Jèhófà;+Torí ìtara rẹ̀ tó ń jó bí iná máa jó gbogbo ayé run,+Nítorí ó máa pa àwọn èèyàn ayé nípakúpa, àní á pa wọ́n yán-án yán-án.”+