Sáàmù 69:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Má sì fi ojú rẹ pa mọ́ fún ìránṣẹ́ rẹ.+ Tètè dá mi lóhùn, nítorí mo wà nínú wàhálà.+ Ìdárò 3:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nítorí ìfẹ́ Jèhófà tí kì í yẹ̀ ni ò jẹ́ ká ṣègbé,+Nítorí àánú rẹ̀ kò ní dópin láé.+