-
Jóẹ́lì 2:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
‘Jèhófà, jọ̀ọ́ ṣàánú àwọn èèyàn rẹ;
Má ṣe jẹ́ kí àwọn èèyàn fi ogún rẹ ṣẹlẹ́yà,
Kó wá di pé àwọn orílẹ̀-èdè á máa jọba lórí wọn,
Tí àwọn èèyàn á fi máa sọ pé, “Ibo ni Ọlọ́run wọn wà?”’+
-