Sáàmù 145:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ìran dé ìran yóò máa yin àwọn iṣẹ́ rẹ;Wọ́n á máa sọ nípa iṣẹ́ ńlá rẹ.+ Àìsáyà 43:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Àwọn èèyàn tí mo dá fún ara mi,Kí wọ́n lè kéde ìyìn mi.+