Sáàmù 44:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ọwọ́ rẹ ni o fi lé àwọn orílẹ̀-èdè jáde,+O sì mú kí àwọn baba ńlá wa máa gbé níbẹ̀.+ O fọ́ àwọn orílẹ̀-èdè, o sì lé wọn jáde.+ Sáàmù 78:55 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 55 Ó lé àwọn orílẹ̀-èdè jáde níwájú wọn;+Ó fi okùn ìdíwọ̀n pín ogún fún wọn;+Ó mú kí àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì máa gbé inú ilé wọn.+ Jeremáyà 2:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Mo gbìn ọ́ bí àjàrà pupa tó dára,+ gbogbo rẹ̀ jẹ́ èso tí kò lábùkù;Báwo lo ṣe wá di ọ̀mùnú àjàrà ilẹ̀ òkèèrè tí kò dára lójú mi?’+
2 Ọwọ́ rẹ ni o fi lé àwọn orílẹ̀-èdè jáde,+O sì mú kí àwọn baba ńlá wa máa gbé níbẹ̀.+ O fọ́ àwọn orílẹ̀-èdè, o sì lé wọn jáde.+
55 Ó lé àwọn orílẹ̀-èdè jáde níwájú wọn;+Ó fi okùn ìdíwọ̀n pín ogún fún wọn;+Ó mú kí àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì máa gbé inú ilé wọn.+
21 Mo gbìn ọ́ bí àjàrà pupa tó dára,+ gbogbo rẹ̀ jẹ́ èso tí kò lábùkù;Báwo lo ṣe wá di ọ̀mùnú àjàrà ilẹ̀ òkèèrè tí kò dára lójú mi?’+