Àìsáyà 63:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Wo ilẹ̀ láti ọ̀run, kí o sì rí iLáti ibùgbé rẹ mímọ́ àti ológo* tó ga. Ìtara rẹ àti agbára rẹ dà,Ìyọ́nú rẹ tó ń ru sókè*+ àti àánú rẹ dà?+ A ti fà wọ́n sẹ́yìn kúrò lọ́dọ̀ mi.
15 Wo ilẹ̀ láti ọ̀run, kí o sì rí iLáti ibùgbé rẹ mímọ́ àti ológo* tó ga. Ìtara rẹ àti agbára rẹ dà,Ìyọ́nú rẹ tó ń ru sókè*+ àti àánú rẹ dà?+ A ti fà wọ́n sẹ́yìn kúrò lọ́dọ̀ mi.