-
Léfítíkù 23:23, 24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Jèhófà ń bá ọ̀rọ̀ tó ń sọ fún Mósè lọ pé: 24 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Ní ọjọ́ kìíní oṣù keje, kí ẹ sinmi, kí ẹ má ṣiṣẹ́ kankan, kí ẹ fi ìró kàkàkí+ kéde rẹ̀ láti máa rántí, yóò jẹ́ àpéjọ mímọ́.
-