Diutarónómì 32:13, 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ó mú kó gun àwọn ibi gíga+ ayé,Kó lè jẹ irè oko.+ Ó fi oyin inú àpáta bọ́ ọÀti òróró látinú akọ àpáta, 14 Bọ́tà ọ̀wọ́ ẹran àti wàrà agbo ẹran,Pẹ̀lú àgùntàn tó dáa jù,*Àwọn àgbò Báṣánì àti àwọn òbúkọ,Pẹ̀lú àlìkámà*+ tó dáa jù;*O sì mu wáìnì tó tinú ẹ̀jẹ̀* èso àjàrà jáde.
13 Ó mú kó gun àwọn ibi gíga+ ayé,Kó lè jẹ irè oko.+ Ó fi oyin inú àpáta bọ́ ọÀti òróró látinú akọ àpáta, 14 Bọ́tà ọ̀wọ́ ẹran àti wàrà agbo ẹran,Pẹ̀lú àgùntàn tó dáa jù,*Àwọn àgbò Báṣánì àti àwọn òbúkọ,Pẹ̀lú àlìkámà*+ tó dáa jù;*O sì mu wáìnì tó tinú ẹ̀jẹ̀* èso àjàrà jáde.