Diutarónómì 24:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “O ò gbọ́dọ̀ ṣe èrú tí o bá ń dá ẹjọ́ àjèjì tàbí ọmọ aláìníbaba,*+ o ò sì gbọ́dọ̀ gba aṣọ opó láti fi ṣe ìdúró.*+
17 “O ò gbọ́dọ̀ ṣe èrú tí o bá ń dá ẹjọ́ àjèjì tàbí ọmọ aláìníbaba,*+ o ò sì gbọ́dọ̀ gba aṣọ opó láti fi ṣe ìdúró.*+