Jeremáyà 22:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ẹ máa dá ẹjọ́ bó ṣe tọ́, kí ẹ sì máa ṣe òdodo. Ẹ gba ẹni tí àwọn oníjìbìtì jà lólè sílẹ̀. Ẹ má ṣe ni àjèjì èyíkéyìí lára, ẹ má ṣèkà sí ọmọ aláìníbaba* èyíkéyìí tàbí opó.+ Ẹ má sì ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀ ní ibí yìí.+
3 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ẹ máa dá ẹjọ́ bó ṣe tọ́, kí ẹ sì máa ṣe òdodo. Ẹ gba ẹni tí àwọn oníjìbìtì jà lólè sílẹ̀. Ẹ má ṣe ni àjèjì èyíkéyìí lára, ẹ má ṣèkà sí ọmọ aláìníbaba* èyíkéyìí tàbí opó.+ Ẹ má sì ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀ ní ibí yìí.+