Míkà 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Mo sọ pé: “Ẹ jọ̀ọ́ ẹ gbọ́, ẹ̀yin olórí ilé Jékọ́bùÀti ẹ̀yin aláṣẹ ilé Ísírẹ́lì.+ Ṣé kò yẹ kí ẹ mọ ohun tó tọ́?
3 Mo sọ pé: “Ẹ jọ̀ọ́ ẹ gbọ́, ẹ̀yin olórí ilé Jékọ́bùÀti ẹ̀yin aláṣẹ ilé Ísírẹ́lì.+ Ṣé kò yẹ kí ẹ mọ ohun tó tọ́?