Jòhánù 10:34, 35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Jésù sọ fún wọn pé: “Ṣebí a kọ ọ́ sínú Òfin yín pé, ‘Mo sọ pé: “ọlọ́run* ni yín”’?+ 35 Tó bá pe àwọn tí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run sọ̀rọ̀ lòdì sí ní ‘ọlọ́run,’+ síbẹ̀ tí a kò lè wọ́gi lé ìwé mímọ́, 1 Kọ́ríńtì 8:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Torí bó tiẹ̀ jẹ́ pé àwọn tí à ń pè ní ọlọ́run wà, ì báà jẹ́ ní ọ̀run tàbí ní ayé,+ bí ọ̀pọ̀ “ọlọ́run” àti ọ̀pọ̀ “olúwa” ṣe wà,
34 Jésù sọ fún wọn pé: “Ṣebí a kọ ọ́ sínú Òfin yín pé, ‘Mo sọ pé: “ọlọ́run* ni yín”’?+ 35 Tó bá pe àwọn tí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run sọ̀rọ̀ lòdì sí ní ‘ọlọ́run,’+ síbẹ̀ tí a kò lè wọ́gi lé ìwé mímọ́,
5 Torí bó tiẹ̀ jẹ́ pé àwọn tí à ń pè ní ọlọ́run wà, ì báà jẹ́ ní ọ̀run tàbí ní ayé,+ bí ọ̀pọ̀ “ọlọ́run” àti ọ̀pọ̀ “olúwa” ṣe wà,