-
2 Kíróníkà 20:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ní àárín ìjọ náà, ẹ̀mí Jèhófà bà lé Jáhásíẹ́lì ọmọ Sekaráyà ọmọ Bẹnáyà ọmọ Jéélì ọmọ Matanáyà ọmọ Léfì látinú àwọn ọmọ Ásáfù.
-