2 Kíróníkà 20:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Móábù+ àti àwọn ọmọ Ámónì+ pẹ̀lú àwọn kan lára àwọn Ámónímù* wá láti bá Jèhóṣáfátì jà. 2 Kíróníkà 20:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ní báyìí, àwọn èèyàn Ámónì àti Móábù pẹ̀lú agbègbè olókè Séírì+ ti wà níbí, àwọn tí o kò yọ̀ǹda fún Ísírẹ́lì láti gba ilẹ̀ wọn nígbà tí wọ́n ń bọ̀ láti ilẹ̀ Íjíbítì. Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yà kúrò lọ́dọ̀ wọn, wọn ò sì pa wọ́n rẹ́.+
20 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Móábù+ àti àwọn ọmọ Ámónì+ pẹ̀lú àwọn kan lára àwọn Ámónímù* wá láti bá Jèhóṣáfátì jà.
10 Ní báyìí, àwọn èèyàn Ámónì àti Móábù pẹ̀lú agbègbè olókè Séírì+ ti wà níbí, àwọn tí o kò yọ̀ǹda fún Ísírẹ́lì láti gba ilẹ̀ wọn nígbà tí wọ́n ń bọ̀ láti ilẹ̀ Íjíbítì. Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yà kúrò lọ́dọ̀ wọn, wọn ò sì pa wọ́n rẹ́.+