-
1 Kíróníkà 5:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Nígbà ayé Sọ́ọ̀lù, wọ́n bá àwọn ọmọ Hágárì jà, wọ́n sì ṣẹ́gun wọn, torí náà, wọ́n ń gbé inú àwọn àgọ́ wọn ní gbogbo ilẹ̀ tó wà ní ìlà oòrùn Gílíádì.
-