-
Àwọn Onídàájọ́ 8:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Séébà àti Sálímúnà wà ní Kákórì, pẹ̀lú àwọn ọmọ ogun wọn, nǹkan bí ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀ẹ́dógún (15,000) ọkùnrin. Àwọn tó ṣẹ́ kù nínú gbogbo ọmọ ogun àwọn Ará Ìlà Oòrùn+ nìyí, torí ọ̀kẹ́ mẹ́fà (120,000) ọkùnrin tó ń fi idà jà ni wọ́n ti pa.
-
-
Àwọn Onídàájọ́ 8:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Nígbà tí Séébà àti Sálímúnà sá, ó lé àwọn ọba Mídíánì méjèèjì bá, ó sì gbá wọn mú, ìyẹn Séébà àti Sálímúnà, jìnnìjìnnì sì bá gbogbo ibùdó náà.
-