Sáàmù 144:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Jèhófà, tẹ àwọn ọ̀run rẹ wálẹ̀ kí o sì sọ̀ kalẹ̀;+Fọwọ́ kan àwọn òkè, kí o sì mú kí wọ́n rú èéfín.+ Náhúmù 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ta ló lè dúró nígbà tó bá ń bínú?+ Ta ló sì lè fara da ooru ìbínú rẹ̀?+ Yóò tú ìbínú rẹ̀ jáde bí iná,Àwọn àpáta á sì fọ́ sí wẹ́wẹ́ nítorí rẹ̀.
5 Jèhófà, tẹ àwọn ọ̀run rẹ wálẹ̀ kí o sì sọ̀ kalẹ̀;+Fọwọ́ kan àwọn òkè, kí o sì mú kí wọ́n rú èéfín.+
6 Ta ló lè dúró nígbà tó bá ń bínú?+ Ta ló sì lè fara da ooru ìbínú rẹ̀?+ Yóò tú ìbínú rẹ̀ jáde bí iná,Àwọn àpáta á sì fọ́ sí wẹ́wẹ́ nítorí rẹ̀.