Oníwàásù 8:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nítorí pé a kò tètè mú ìdájọ́ ṣẹ lórí ìwà burúkú,+ ọkàn àwọn èèyàn le gbagidi láti ṣe búburú.+