Àìsáyà 57:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 “Màá dá èso ètè. Màá fún ẹni tó wà lọ́nà jíjìn àti ẹni tó wà nítòsí ní àlàáfíà tí kò lópin,”+ ni Jèhófà wí,“Màá sì wò ó sàn.”
19 “Màá dá èso ètè. Màá fún ẹni tó wà lọ́nà jíjìn àti ẹni tó wà nítòsí ní àlàáfíà tí kò lópin,”+ ni Jèhófà wí,“Màá sì wò ó sàn.”