Sáàmù 89:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Òdodo àti ìdájọ́ òdodo ni ìpìlẹ̀ ìtẹ́ rẹ;+Ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́ dúró níwájú rẹ.+