Sáàmù 72:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ìyìn ni fún Jèhófà Ọlọ́run, Ọlọ́run Ísírẹ́lì,+Òun nìkan ló ń ṣe àwọn ohun àgbàyanu.+ Dáníẹ́lì 6:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ó ń gbani sílẹ̀,+ ó ń gbani là, ó ń ṣe àwọn iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu ní ọ̀run àti ní ayé,+ torí ó gba Dáníẹ́lì sílẹ̀ lọ́wọ́* àwọn kìnnìún.”
27 Ó ń gbani sílẹ̀,+ ó ń gbani là, ó ń ṣe àwọn iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu ní ọ̀run àti ní ayé,+ torí ó gba Dáníẹ́lì sílẹ̀ lọ́wọ́* àwọn kìnnìún.”