Sáàmù 78:68 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 68 Àmọ́, ó yan ẹ̀yà Júdà,+Òkè Síónì, èyí tí ó nífẹ̀ẹ́.+ Sáàmù 132:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nítorí Jèhófà ti yan Síónì;+Ó fẹ́ kó jẹ́ ibùgbé rẹ̀, ó ní:+