Sáàmù 46:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Odò kan wà tí ṣíṣàn rẹ̀ ń mú kí ìlú Ọlọ́run máa yọ̀,+Àgọ́ ìjọsìn mímọ́ títóbi ti Ẹni Gíga Jù Lọ.