-
Sáàmù 116:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Kí ọkàn* mi rí ìsinmi lẹ́ẹ̀kan sí i,
Nítorí Jèhófà ti fi inú rere hàn sí mi.
-
-
Sáàmù 119:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ṣe dáadáa sí èmi ìránṣẹ́ rẹ,
Kí n lè wà láàyè, kí n sì máa pa ọ̀rọ̀ rẹ mọ́.+
-