Sáàmù 71:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé o ti mú kí n rí ọ̀pọ̀ wàhálà àti àjálù,+Mú kí n sọ jí lẹ́ẹ̀kan sí i;Gbé mi dìde láti inú kòtò* ilẹ̀ ayé.+
20 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé o ti mú kí n rí ọ̀pọ̀ wàhálà àti àjálù,+Mú kí n sọ jí lẹ́ẹ̀kan sí i;Gbé mi dìde láti inú kòtò* ilẹ̀ ayé.+