Sáàmù 46:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 46 Ọlọ́run ni ibi ààbò wa àti okun wa,+Ìrànlọ́wọ́ tó wà lárọ̀ọ́wọ́tó ní àkókò wàhálà.+