-
Jóòbù 19:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ó ti lé àwọn arákùnrin mi jìnnà réré sí mi,
Àwọn tó sì mọ̀ mí ti kúrò lọ́dọ̀ mi.+
-
-
Sáàmù 38:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Àwọn ọ̀rẹ́ mi àti àwọn ẹlẹgbẹ́ mi yẹra fún mi nítorí ìyọnu tó dé bá mi,
Àwọn ojúlùmọ̀ tó sún mọ́ mi sì ta kété sí mi.
-