1 Kíróníkà 16:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Àwọn tó wà pẹ̀lú wọn ni Hémánì àti Jédútúnì+ pẹ̀lú ìyókù àwọn ọkùnrin tí a fi orúkọ yàn láti máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà,+ nítorí “ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé”;+ Àìsáyà 54:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àwọn òkè ńlá lè ṣí kúrò,Àwọn òkè kéékèèké sì lè mì tìtì,Àmọ́ ìfẹ́ mi tí kì í yẹ̀ ò ní kúrò lọ́dọ̀ rẹ,+Májẹ̀mú àlàáfíà mi ò sì ní mì,”+ ni Jèhófà, Ẹni tó ń ṣàánú rẹ wí.+
41 Àwọn tó wà pẹ̀lú wọn ni Hémánì àti Jédútúnì+ pẹ̀lú ìyókù àwọn ọkùnrin tí a fi orúkọ yàn láti máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà,+ nítorí “ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé”;+
10 Àwọn òkè ńlá lè ṣí kúrò,Àwọn òkè kéékèèké sì lè mì tìtì,Àmọ́ ìfẹ́ mi tí kì í yẹ̀ ò ní kúrò lọ́dọ̀ rẹ,+Májẹ̀mú àlàáfíà mi ò sì ní mì,”+ ni Jèhófà, Ẹni tó ń ṣàánú rẹ wí.+