1 Kíróníkà 17:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “‘“Nígbà tí o bá kú, tí o sì lọ síbi tí àwọn baba ńlá rẹ wà, màá gbé ọmọ* rẹ dìde lẹ́yìn rẹ, ọ̀kan lára àwọn ọmọ rẹ,+ màá sì fìdí ìjọba rẹ̀ múlẹ̀.+ Ìfihàn 22:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “‘Èmi Jésù rán áńgẹ́lì mi láti jẹ́rìí àwọn nǹkan yìí fún ọ nítorí àwọn ìjọ. Èmi ni gbòǹgbò àti ọmọ Dáfídì+ àti ìràwọ̀ òwúrọ̀ tó mọ́lẹ̀ rekete.’”+
11 “‘“Nígbà tí o bá kú, tí o sì lọ síbi tí àwọn baba ńlá rẹ wà, màá gbé ọmọ* rẹ dìde lẹ́yìn rẹ, ọ̀kan lára àwọn ọmọ rẹ,+ màá sì fìdí ìjọba rẹ̀ múlẹ̀.+
16 “‘Èmi Jésù rán áńgẹ́lì mi láti jẹ́rìí àwọn nǹkan yìí fún ọ nítorí àwọn ìjọ. Èmi ni gbòǹgbò àti ọmọ Dáfídì+ àti ìràwọ̀ òwúrọ̀ tó mọ́lẹ̀ rekete.’”+