1 Sámúẹ́lì 2:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Kò sí ẹni tí ó mọ́ bíi Jèhófà,Kò sí ẹlòmíràn, àfi ìwọ,+Kò sì sí àpáta tí ó dà bí Ọlọ́run wa.+ Sáàmù 84:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,Aláyọ̀ ni ẹni tó gbẹ́kẹ̀ lé ọ.+