Àìsáyà 30:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Torí ìrànlọ́wọ́ Íjíbítì ò wúlò rárá.+ Torí náà, mo pe ẹni yìí ní: “Ráhábù,+ tó jókòó jẹ́ẹ́.”