-
Ẹ́kísódù 14:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Ni Jèhófà bá sọ fún Mósè pé: “Na ọwọ́ rẹ sórí òkun, kí omi náà lè pa dà, kó sì bo àwọn ará Íjíbítì, àwọn kẹ̀kẹ́ ogun wọn àti àwọn agẹṣin wọn.”
-