1 Kíróníkà 17:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Màá yan ibì kan fún àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì, màá fìdí wọn kalẹ̀, wọ́n á sì máa gbé ibẹ̀ láìsì ìyọlẹ́nu mọ́; àwọn ẹni burúkú kò ní pọ́n wọn lójú* mọ́, bí wọ́n ti máa ń ṣe tẹ́lẹ̀,+
9 Màá yan ibì kan fún àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì, màá fìdí wọn kalẹ̀, wọ́n á sì máa gbé ibẹ̀ láìsì ìyọlẹ́nu mọ́; àwọn ẹni burúkú kò ní pọ́n wọn lójú* mọ́, bí wọ́n ti máa ń ṣe tẹ́lẹ̀,+