2 Sámúẹ́lì 22:47 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 47 Jèhófà wà láàyè! Ìyìn ni fún Àpáta mi!+ Kí a gbé Ọlọ́run tó jẹ́ àpáta ìgbàlà mi ga.+ Sáàmù 18:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jèhófà ni àpáta gàǹgà mi àti odi ààbò mi àti Ẹni tó ń gbà mí sílẹ̀.+ Ọlọ́run mi ni àpáta mi,+ ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,Apata mi àti ìwo* ìgbàlà mi,* ibi ààbò mi.*+
2 Jèhófà ni àpáta gàǹgà mi àti odi ààbò mi àti Ẹni tó ń gbà mí sílẹ̀.+ Ọlọ́run mi ni àpáta mi,+ ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,Apata mi àti ìwo* ìgbàlà mi,* ibi ààbò mi.*+