Ìṣe 13:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Bí Ó ṣe jí i dìde nínú ikú, tí kò sì jẹ́ kó pa dà sí ara tó lè díbàjẹ́ mọ́, ó sọ ọ́ lọ́nà yìí pé: ‘Màá fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ tí mo ṣèlérí fún Dáfídì hàn sí ọ, èyí tó jẹ́ òtítọ́.’*+
34 Bí Ó ṣe jí i dìde nínú ikú, tí kò sì jẹ́ kó pa dà sí ara tó lè díbàjẹ́ mọ́, ó sọ ọ́ lọ́nà yìí pé: ‘Màá fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ tí mo ṣèlérí fún Dáfídì hàn sí ọ, èyí tó jẹ́ òtítọ́.’*+