2 Sámúẹ́lì 23:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ǹjẹ́ kì í ṣe bí ilé mi ṣe rí nìyẹn lójú Ọlọ́run? Torí ó ti bá mi dá májẹ̀mú ayérayé,+Tó wà létòlétò, tó sì wà lábẹ́ ààbò. Nítorí ó jẹ́ ìgbàlà mi látòkèdélẹ̀ àti gbogbo ìdùnnú mi,Ǹjẹ́ kì í ṣe ìdí tó fi ń mú kó gbilẹ̀+ nìyẹn? Sáàmù 89:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Mi ò ní da májẹ̀mú mi,+Mi ò sì ní yí ohun tí ẹnu mi ti sọ pa dà.+
5 Ǹjẹ́ kì í ṣe bí ilé mi ṣe rí nìyẹn lójú Ọlọ́run? Torí ó ti bá mi dá májẹ̀mú ayérayé,+Tó wà létòlétò, tó sì wà lábẹ́ ààbò. Nítorí ó jẹ́ ìgbàlà mi látòkèdélẹ̀ àti gbogbo ìdùnnú mi,Ǹjẹ́ kì í ṣe ìdí tó fi ń mú kó gbilẹ̀+ nìyẹn?