Sáàmù 41:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ìyìn ni fún Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì Títí láé àti láéláé.*+ Àmín àti Àmín. Sáàmù 72:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ìyìn ni fún Jèhófà Ọlọ́run, Ọlọ́run Ísírẹ́lì,+Òun nìkan ló ń ṣe àwọn ohun àgbàyanu.+