2 Pétérù 3:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Síbẹ̀, ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, ẹ má gbàgbé pé lójú Jèhófà* ọjọ́ kan dà bí ẹgbẹ̀rún ọdún àti pé ẹgbẹ̀rún ọdún dà bí ọjọ́ kan.+
8 Síbẹ̀, ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, ẹ má gbàgbé pé lójú Jèhófà* ọjọ́ kan dà bí ẹgbẹ̀rún ọdún àti pé ẹgbẹ̀rún ọdún dà bí ọjọ́ kan.+