Òwe 24:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Tí o bá sọ pé: “Ṣebí a ò mọ̀ nípa rẹ̀,”Ṣé Ẹni tó ń ṣàyẹ̀wò ọkàn* kò mọ̀ ni?+ Bẹ́ẹ̀ ni, Ẹni tó ń wò ọ́* máa mọ̀Yóò sì san ẹnì kọ̀ọ̀kan lẹ́san gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ rẹ̀.+ Hébérù 4:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Kò sí ìṣẹ̀dá kankan tó fara pa mọ́ ní ojú rẹ̀,+ àmọ́ ohun gbogbo wà ní ìhòòhò, ó sì wà ní gbangba lójú ẹni tí a gbọ́dọ̀ jíhìn fún.+
12 Tí o bá sọ pé: “Ṣebí a ò mọ̀ nípa rẹ̀,”Ṣé Ẹni tó ń ṣàyẹ̀wò ọkàn* kò mọ̀ ni?+ Bẹ́ẹ̀ ni, Ẹni tó ń wò ọ́* máa mọ̀Yóò sì san ẹnì kọ̀ọ̀kan lẹ́san gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ rẹ̀.+
13 Kò sí ìṣẹ̀dá kankan tó fara pa mọ́ ní ojú rẹ̀,+ àmọ́ ohun gbogbo wà ní ìhòòhò, ó sì wà ní gbangba lójú ẹni tí a gbọ́dọ̀ jíhìn fún.+