ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 19:34, 35
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 34 Àmọ́ Básíláì sọ fún ọba pé: “Ọjọ́* mélòó ló kù tí màá lò láyé tí màá fi bá ọba lọ sí Jerúsálẹ́mù? 35 Ẹni ọgọ́rin (80) ọdún ni mí lónìí.+ Ṣé mo ṣì lè fi òye mọ ìyàtọ̀ láàárín rere àti búburú? Ṣé èmi ìránṣẹ́ rẹ lè mọ adùn ohun tí mò ń jẹ àti ohun tí mò ń mu? Ṣé mo ṣì lè gbọ́ ohùn àwọn akọrin + lọ́kùnrin àti lóbìnrin? Ṣé ó wá yẹ kí ìránṣẹ́ rẹ tún jẹ́ ẹrù fún olúwa mi ọba?

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́