ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 33:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Jìnnìjìnnì ti bá àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ní Síónì;+

      Àwọn apẹ̀yìndà ń gbọ̀n rìrì:

      ‘Èwo nínú wa ló lè gbé níbi tí iná tó ń jẹni run wà?+

      Èwo nínú wa ló lè bá ọwọ́ iná tí kò ṣeé pa gbé?’

  • Lúùkù 12:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Ṣùgbọ́n màá fi ẹni tí ẹ máa bẹ̀rù hàn yín: Ẹ bẹ̀rù Ẹni tó jẹ́ pé lẹ́yìn tó bá pani, ó ní àṣẹ láti sọni sínú Gẹ̀hẹ́nà.*+ Àní, mò ń sọ fún yín, Ẹni yìí ni kí ẹ bẹ̀rù.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́