-
Sáàmù 89:46Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
46 Jèhófà, ìgbà wo lo máa fi ara rẹ pa mọ́ dà? Ṣé títí láé ni?+
Ṣé ìbínú ńlá rẹ yóò máa jó lọ bí iná ni?