Òwe 12:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Kò sí jàǹbá tó máa ṣe olódodo,+Àmọ́ ọ̀pọ̀ àjálù ló máa dé bá àwọn ẹni burúkú.+