Lúùkù 10:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ẹ wò ó! Mo ti fún yín ní àṣẹ láti fi ẹsẹ̀ tẹ àwọn ejò àti àkekèé mọ́lẹ̀ àti àṣẹ lórí gbogbo agbára ọ̀tá,+ kò sì ní sí ohunkóhun tó máa pa yín lára.
19 Ẹ wò ó! Mo ti fún yín ní àṣẹ láti fi ẹsẹ̀ tẹ àwọn ejò àti àkekèé mọ́lẹ̀ àti àṣẹ lórí gbogbo agbára ọ̀tá,+ kò sì ní sí ohunkóhun tó máa pa yín lára.