-
Sáàmù 138:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Bí mo bá tiẹ̀ ń rìn nínú ewu, wàá dá ẹ̀mí mi sí.+
O na ọwọ́ rẹ sórí àwọn ọ̀tá mi tó ń bínú;
Ọwọ́ ọ̀tún rẹ yóò gbà mí là.
-
-
Àìsáyà 43:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Tí o bá rin inú iná kọjá, kò ní jó ọ,
Ọwọ́ iná ò sì ní rà ọ́.
-